Episode Synopsis "Imoran Nipa Ilosiwaju."
Ilosiwaju dara. Sugbon Ilosiwaju pe orisirisi. Ilosiwaju lati owo Esu lo po lode oni. Ibukun Oluwa lo nmu ni la lai fi laala si. Esu ki i fun ni ni nkan ko ma siregun. Sugbon Oba a fun ni tan masiregun ko kuro lori ite. Suuru se pataki. Ile aimed laba owo, ile aiye la o fi sile si lo. Oluwa yo gbo adura wa. Ile Yoruba ko ni baje o. Amin.
Listen "Imoran Nipa Ilosiwaju."
More episodes of the podcast KNOWLEDGE OF CHRIST
- Prayer For New MONTH
- Adura
- ADURA IPARI OSU AUGUST 2018 ATI ISEGUN.
- PRAYER OF DELIVERANCE
- Adura Isegun
- ADURA FUN ISEGUN ATI IWOSAN
- Early MORNING Prayer By Pastor OLUSEGUN ONI
- Adura Owuro
- Adura Fun Ojo Gbogbo
- It Is Well With My Soul
- E Je Ka Fi Inu Didun Yin Oluwa.
- Orin Abo Ati Ope
- Random PRAYERS.
- Imoran Nipa Ilosiwaju.