ADURA OWURO

ADURA OWURO

Adekusile Adedayo Shedrack's podcast

17/05/2020 5:33AM

Episode Synopsis "ADURA OWURO"

ADURA ISEJU MEEDOGUNOniwasu 10vs8Eniti o wà iho ni yio bó sinu rè; ati eniti o si njá ogbà tùtù, Eko yio si bu u San.KOKO ADURA1. OLUWA Modupe lowo re Nitori pe Iwo Olorun yio GBA ija mi ja, oni fi mi le ife ota lowo ni oruko Jesu2. Awon Ese to mo dawole ti koni je ki Iwo Olorun o gbo ADURA mi Oluwa dariji mi, ki o si pa ese mi re ni oruko Jesu3. Oluwa lodun Yi Eni ba gbe Owo Ogun soke pe o in ofi na mi, Oluwa je ko fi na ara re4. Oluwa talo sare Kiri Nitori Oro mi lati ba temi je Oluwa je ko kose ko subu5. OLUWA ki Ipinnu ota to se lemi Lori Lodun Yi Oluwa fi Ina ati Ara re kolu won6. OLUWA Eda Eniyan to wa iranlowo lo si odo okunkun lati bate mi je Oluwa fi ibinu kolu7. OLUWA bo ti wu ki ota se to, lodun Yi Oluwa maje nsubu sowo ota8. OLUWA lodun Yi nibi kibi ti mi o ti le ja fun arami, Oluwa loja funmi mine9. OLUWA Ni Iru Akoko Bayi ti a wa ni Nigeria Oluwa ma bo emi ati Ile mi Maje ki asiri mi o tu10. Dupe lowo Olorun Nitori oti gbo ADURA re Amin Ni oruko Jesu

Listen "ADURA OWURO"

More episodes of the podcast Adekusile Adedayo Shedrack's podcast