Ipade Pelu Olorun {¡}-{Iwo Ati Olorun Nikan};Orin-Dafidi 8:3&4

25/02/2024 19 min Episodio 640

Listen "Ipade Pelu Olorun {¡}-{Iwo Ati Olorun Nikan};Orin-Dafidi 8:3&4"

Episode Synopsis

Okan l'ara awon ohun ti o şe pataki ti a ba fe ni ajoşepò ti o dara, dun, danmoran pelu enikeni tii ba a jé tabi ti a yan l'aayo ni riri daju pe a n ya akoko s'oto loorekoore l'ati maa pade, wa papò, s'òrò ojukoroju pelu won. Bi a ba wa n s'òrò nipa ajoşepo eniyan pelu Olorun nko/Olorun pelu eniyan....🤔.....d'arapo mo wa fun eko yi....👩‍💻👨‍💻🧑‍💻👨‍💻👩‍💻🧑‍💻....


Kan si wa l'ori;
[email protected]/
+447417522082