Ètò Èro Ìjìnlè Fún Ìrìnná{v}-{Èro Ijinle Ti Igbalode}

30/03/2025 22 min Episodio 718

Listen "Ètò Èro Ìjìnlè Fún Ìrìnná{v}-{Èro Ijinle Ti Igbalode}"

Episode Synopsis

D'arapo mo wa l'ati tesiwaju wiwo oro Olorun (bibeli) gege bi ipese itosona ti igbalode ti a gbe kale fun Kristieni l'oni nigbati a o ma ko eko pata l'ati inu iwe awon oba keji(2 kings) ati Nehemiah🔎📖📖📖