Agbara Idalare ninu Kristi

16/11/2019 12 min

Listen "Agbara Idalare ninu Kristi"

Episode Synopsis

Idalebi je oun to wa fun awon ti ko ni Krist Sugbon, bi onigbagbo ba ni idalebi okan nigbagbo, ise satani ni, ko si ye be. Eyi ama mu idena ati ailosiwaju ba ise iranse onigbagbo ninu aye ati irin ajo temi, eyi lo mu Oro Olorun yii wa, kiole tan imole si okan wa fun oye nikikun si nipase ori oro wa. Nitorina, gbo kiosi fi ranse si awon elomi lati le je alabunkun fun si. E se pupo.