ATOTO ARERE BY OLADEJO OKEDIJI

ATOTO ARERE BY OLADEJO OKEDIJI

Por: OLADEJO OKEDIJI
IBON NRO GBAMUGBAMU L'OSAN GANGAN. AARO KUTUKUTU NI ISELE NLA TI NSE TI GONGO NSO TITI D'OJO ALE KERERE. AKASE BO BA D'OGANJO, IBON O KAN MAA YOOFIN L'ENU NI, GBAMUGBAMU O NIII DUN MON NITORI AWON TI YIO TI KU TI KU, WON M'OWO O WON O M'OWO O. ALARINFESESI YI O SI TI FI NKAN GBARA, OHUN GBOGBO A WAA PA KESE.ABEBE ALABA A SI TUN TI FI IBI PELEBE RE LELE.OWE, IJINLE ORO, AFIWE ATI OGIDI EDE YORUBA NI A FII DA AWON IWE OLADEJO OKEDIJI MON.IWE ATOTO ARERE YI NI A LEE PE NI EWE NLA NITORI NINU RE NI GBOGBO AWON NKAN TI A KA SOKE YI PIN SI.IWE NAA DUN, O JU OYIN LO.
1 episodios disponibles

Latest episodes of the podcast ATOTO ARERE BY OLADEJO OKEDIJI